Wake Up – Zlatan

Download Wake Up by Zlatan. Omoniyi Temidayo Raphael, known professionally as Zlatan Ibile, is a Nigerian rapper, singer, songwriter, musician, and dancer. From Ijurin Ekiti, Ijero local government area, Ekiti state He is the CEO and founder of Zanku records. listen to Zamorra songs free online here @ SOUNDOFNAIJA

CLICK to PLAY/DOWNLOAD the song

LYRICS

Ayii ayii ayii
Wo emi sọkalẹ
Ibile
Sọkalẹ
Kapachimerimeripako santariteteruwa
Ọya when I wake up in the morning Spellz
Modupé fi Ọlọrun
It wasn’t really funny
Kinto gba débi Kinto gbà débi
When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn’t really funny
Kinto gbà débi ha wo
Ọdọ yi ba yọ mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lo yo mi oh yeah
Ọdọ yi ba yọ mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lọ yo mi oh
Kinto ba debi kúrò bẹ
Wọ them say love na one tin tin
Na so this ilé aiye sef gon bintin
A jo rin nígbà yẹn ni a’dẹ mọ ni olówó
Ti kpa ma fi àkara fún mẹ koko
Everyday lafin she adura
Ki Jésù ranti wa ko ma j’awa ni kan ni nepa ma wa ja’na wà
Showers of blessing lẹ’npe
Ojú tí kún palour wa
Tori every time t’ojo ba rọ o ma leak lati roof wa
And I wan build this legacy for my family
Before I komot for house I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbọ’kan le lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ni iwọ pe Jesu ni mo pe to dẹ pick call mí
When I wake up in the morning
Modupé f’ore Ọlọ’un
It wasn’t really funny
Kinto ba debi kinto ba debi
When I wake up in the morning
Modupé f’ore Ọlọ’un
It wasn’t really funny
Kinto ba debi kinto ba debi ha wo
Ọta yi ba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lo yo mi oh
Ọdọ yi ba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lọ yo mi
Kinto ba debi ah ah ah
Wọ èmi re èmi re
Mo wà d’ẹni tó rà benz
Èmi re èmi re
Mo wa dẹni tó wà fresh
Èmi re
Ọmọlẹ ti olùwà gbogo fun
E ni binu e so fu pe ologo ni ko filẹ
Mọ hussle Toronto oh
Nínú òtútù ni nínú orun
Ko le da fun mi
Ki ma bọ kọ ni rara ko ki sho’un
Mọn ti fresh telé telé woni on shoun
Awọn l’abọsi awọn gbeborun
And I wan build this legacy for my family
Before I komot for house I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbọ’kan le lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ni iwọ pe Jesu ni mo pe to dẹ pick call mí
Ota yi ba yọ mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lo yo mi oh
Ọta yi ba yọ mi
Shebi adura momsi àti popsi mi
Ma lọ yo mi
Kinto ba debi
Spellz
Sweet
 

DOWNLOAD MP3

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*